Adura lilo si masalasi

Ire Olohun fi imole si inu okan mi, ki o si fi imole si ori ahon mi, ki o si fi imole si igboran mi, ki o si fi imole sibi iriran mi, ki o si fi imole si oke mi, ki o si fi imole si isale mi, ki o si fi imole si apa otun mi, ki o si fi imole si apa alaafia mi, ki o si fi imole si iwaju mi, ki o si fi imole si eyin mi, ki o si fi imole si inu emi mi, ki o si se imole mi ni titobi, ki o si se imole fun mi, ki o si semi ni imole, Ire Oluwa Allaah fun mi ni imole, ki o si fi imole si inu isan ara mi, atipe se imole si inu eran ara mi, ki o si fi imole si inu eje mi, ki o si fi imole si inu irun mi, ki o si fi imole si awo ara mi. (1) ................................. (1) wo gbogbo awon gbolohun yi ninu Al-Bukhaari, 11/116. pelu number 6316, ati Muslim, 1/526, ati 529, ati 530, pelu number 763. (2) At-Tirmidhiy, 5/483, pelu number 3419. (3) Bukhaari gbe e jade ninu tira AL-Adabul Mufrid, pelu number 695, oju ewe 258 ti Al-Albaaniy si so pe afiti re ni alaafia ninu tira Al-Adabul Mufrid, pelu number 536. (4) Ibnu Ajar wi i ninu tira Fat'hul Baari, o si fi ti sodo Ibnu Abi Aasim ninu tira Ad-Duaau, wo Al-Fat'hu 11/118, o wa so pe: o si ko isesi meedogbon jo lati inu oniranran egbawa.

API