Adura ti alaare to ti ja okan kuro nibi igbesi aye re

Olohun, fori jin mi ki O si tun kemi, ki O si dami po mo alabarin to ga julo

Anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba - je enikan to je wipe nigba iku re, o n ti owo re mejeeji bo inu omi, yio si fi mejeeji pa oju re yio wa so wipe: Ko si Oba Kankan ti ijosin ododo tosi ayafi Olohun, Dajudaju ihunrira nbe fun iku

Ko si Oba ti ijosin tosi ni ododo ayafi Olohun, ati pe Olohun Oba ni Oba ti o tobi julo, ko si Oba ti ijosin tosi ni ododo ayafi Olohun ni oun nikan ti ko si orogun fun Un, ko si Oba ti ijosin tosi ni ododo ayafi Olohun, Oba to ja si wipe ti E ni ola nse, ti E ni ope nse, ko si eniti ijosin tosi ni ododo ayafi Olohun, ko si ete Kankan ati agbara kan ti yio maa be ayafi pelu Olohun

API