Adura ti a maa nse ti alaawe bafe sinu

Ongbe ti lo bayii, awon isan si ti tutu, laada si ti fi ese mule ti Olohun ba fe

Olohun, emi nbe O pelu ike Re to je wipe o ko gbogbo nkan sinu wipe ki O se aforijin fun mi

API