Adura ti a maa nse ti aba salamo leyin irun witiri

Mimo ni fun Olohun Olola, Oba Mimo… A o so o ni igba meta, Eleeketa yio so o sita pelu fi fa ohun re gun ti yio si so pe: Oluwa ti O ni awon malaika ati Jibriil oga won

API