Ohun ti Olohun fi ma nso eeyan kuro lowo Dajjaal

Eniti o ba ha aaya mewa ni ibere Suuratul Kahf, won a so o kuro lowo Dajjaal. Ati iwasora pelu Olohun kuro nibi fitina re ni ipari ataaya igbeyin nibi gbogbo irun kookan.

API