Adura jijade ninu ile egbin

Mo toro aforijin Re. (1) ................................ (1) Awon ti won ni tira Sunan ni won gbe e jade ayafi An-Nasaai, ohun naa si gbe e jade ninu tira re ti a npe ni Amalul Yami wal Lailah, pelu number 79, Abu Dauud, pelu number 30, At-Tirmidhiy, pelu number 7, ati Ibnu Maajah, pelu number 300, ti Al-Albaaniy si so wipe o ni alaafia ninu Sohiihu Sunani Abi Daaud, 1/19

API