Adura nigba ti a ba fe wo inu ile

Pelu oruko Olohun ni a fi wole atipe pelu oruko Re ni a fi jade atipe Allaah Oluwa wa ni a gbara le, leyin igbayen ki o wa salamo si awon ara ile. (1) ............................... (1) Abu Daaud lo gbe e jade, 4/325, 5096, ti Alfa agba Ibnu Baaz si sope afiti re daa ninu tira Tuhfatul Akh'yaar, oju ewe 28, atipe ninu AS-Sohiih: ((ti omoniyan kan pa wo inu ile re ti o si ranti Olohun nigbati o fe wo o, ati nibi ounje re, Ash-shaitoon o so pe: ko si ibusun fun yin o, ko si si ounje ale fun yin)), Muslim, pelu number 2018.

API