Adura ti a maa nse nigba ti a ba jeun tan

Ope ni fun Olohun ti o se wipe O fun mi ni ounje yii je ti O si pese re fun mi ti ko ki n se ete Kankan lati odo mi ati agbara

Ope ni fun Olohun, o pe topo to daa to si ni ibukun ninu, ope ti n ko le du ti yoo fi dogba pelu oore ti Olohun se fun mi, ope ti ko se e pati ti ko si see ma se rara.

API