Ohun ti Musulumi o maa so nigbati o ba yin Musulumi

Anabi – ki ike ati ola Olohun maa ba a – so pe: Ti enikookan yin ba je eniti o nyin ore re ti ko si ibuye ko ya so pe: mo nlero re bee Olohun lo si ma amodaju re, mio si se afoma enikankan le Olohun lowo, mo nlero re – ti o ba mo nkan yen – bai bai.

API